Boekomslag van Lati Inu Dáyárì Ọmọ Kilásì Àárin Kan

Lati Inu Dáyárì Ọmọ Kilásì Àárin Kan

Iriri Ọmọde

Beschrijving van het boek

Àpèjúwe KúkúrúNinu ìwé yii Mo ti ṣàpèjúwe awọn akitiyan igbé ayé mi ni kọlẹji. Mo pinnu lati kọ ìwé yi nigbati ó jẹ wipe n kò ni awọn ọrẹ, n kò mọ bi awọn ìdánwò ipari simẹsità ti yunifásítì se ri, ti mo si pàdánù awọn ìdánwò mi. Lẹhin ọpọlọpọ akitiyan, mo se awọn ìdánwò ipari simẹsità, mo si kọ awọn iriri mi ni kọlẹji sinu ìwé yi.

Àpèjúwe Ní KíkúnNinu ìwé yii Mo ti ṣàpèjúwe awọn akitiyan igbé ayé mi ni kọlẹji. Mo pinnu lati kọ ìwé yi nigbati ó jẹ wipe n kò ni awọn ọrẹ, n kò mọ bi awọn ìdánwò ipari simẹsità ti yunifásítì se ri, ti mo si pàdánù awọn ìdánwò mi. Lẹhin ọpọlọpọ akitiyan, mo se awọn ìdánwò ipari simẹsità, mo si kọ awọn iriri mi ni kọlẹji sinu ìwé yi.

PUBLISHER: TEKTIME

Auteur.Ashok Kumawat